Ileeṣẹ Aṣọbode Naijiria ni iroyin ofege ni pe awọn ti ẹnubode pa ni Sẹmẹ. Ogbẹni Joseph Attah to jẹ agbẹnusọ fun ileeṣẹ aṣọbode Naijiria ni awọn ko ti bode Naijiria ati ti orilẹ-ede Benin Republic pa ...